Ọ̀rọ̀ ìṣe ni ọ̀rọ̀ tí ó ń fi ohun tí a ń ṣe lọ́wọ́ tí a ti ṣe kọjá tàbí ohun tí a óò ma ṣe lọ́jọ́ iwájú hàn nínú gbólóhùn.
Èyí ni kókó inú gbólóhùn èdè Yorùbá, òhun ni ó wà láàrin Olúwa àti àbọ̀, ó lè ṣíwájú ólùwa ó sì lè síwájú àbọ̀, òpómúléró inú gbólóhùn ni ọ̀rọ̀ ìṣe jẹ́.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Ọ̀rọ̀ ìṣe, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.