Tunisia

Tùnísíà (US /tuːˈniːʒə/ two-NEE-zhə or UK /tjuːˈnɪziə/ tew-NIZ-iə; Lárúbáwá: تونس‎ Tūnis pronounced ), lonibise bi Orile-ede Olómìnira ara Tùnísíà (Lárúbáwá: الجمهورية التونسية‎ al-Jumhūriyyah at-Tūnisiyyah Àdàkọ:IPAc-ar), ni orile-ede apaariwajulo ni Áfríkà.

O je orile-ede Maghreb kan, be si ni o ni bode mo Àlgéríà ni iwoorun, Libya ni guusuilaorun, ati Omiokun Mediterraneani si ariwa ati ilaorun. Aala re je 165,000 square kilometres (64,000 sq mi), pelu idiyele alabugbe to je egbegberun 10.4. Oruko re wa lati inu oruko oluilu re Tunis to budo si ariwa-ilaorun.

Orílẹ̀-èdè Olómìnira ará Tùnísíà
Tunisian Republic

الجمهورية التونسية
al-Jumhūriyyah at-Tūnisiyyah
Coat of arms ilẹ̀ Tùnísíà
Coat of arms
Motto: حرية، نظام، عدالة
"Ḥurriyyah, Niẓām, ‘Adālah"
"Liberty, Order, Justice"
Orin ìyìn: "Humat al-Hima"
"Defenders of the Homeland"
Location of Tùnísíà
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Tunis
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaArabic
Orúkọ aráàlúTunisian
ÌjọbaUnitary Presidential Republic
• President
Kais Saied
• Prime Minister
Ahmed Hachani
• Prime Minister-designate
Mehdi Jomaa
Independence
• from France
March 20, 1956
Ìtóbi
• Total
163,610 km2 (63,170 sq mi) (92nd)
• Omi (%)
5.0
Alábùgbé
• 2014 estimate
10,982,754 (79th)
• 2011 census
11,245,284
• Ìdìmọ́ra
63/km2 (163.2/sq mi) (133rd (2005))
GDP (PPP)2011 estimate
• Total
$96.001 billion
• Per capita
$9,025.067
GDP (nominal)2011 estimate
• Total
$43.684 billion
• Per capita
$4,106.747
Gini (2000)39.8
medium
HDI (2010) 0.683
Error: Invalid HDI value · 81st
OwónínáTunisian dinar (TND)
Ibi àkókòUTC+1 (CET)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+1 (not observed)
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù216
ISO 3166 codeTN
Internet TLD.tn .تونس

Tunisia je orile-ede to kerejulo to budo si eba oke Atlas. Guusu orile-ede na je kiki aginju Sahara, pelu eyi to to je kiki ile olora ati eti okun 1,300 kilometres (810 mi). Awon mejeji ko ipa pataki igba atijo, akoko pelu ilu Carthage awon Punic, leyin re bi igberiko ile Romu ni Africa, to gbajumo bi "apere onje /bread basket" ile Romu. Leyin re, Tunisia bo so wo awon Vandals ni orundun 5k LK, awon Byzantine ni orundun 6k, ati awon Arabu ni orundun 8k. Labe Ileobaluaye Ottomani, Tunisia je mimo bi "Iluoba Tunis/Regency of Tunis". O bo sowo ibiabo Fransi ni 1881. Leyin ominira ni 1956 orile-ede na di "Ileoba Tunisia" leyin ijoba Lamine Bey ati Iran-oba Husainid. Pelu ifilole Orile-ede Olominira ara Tunisia ni July 25, 1957, olori aseolorile-ede Habib Bourguiba di aare akoko.



Akiyesi

Itokasi

Tags:

LibyaMaghrebMediterranean SeaNorth AfricaTunisen:WP:IPA for Arabicen:Wikipedia:IPA for Englishen:Wikipedia:Pronunciation respelling keyÀlgéríàÁfríkàÈdè Arabiki

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ISO/IEC 8859-7Máàdámidófò17 AprilLalisa ManobalISO/IEC 17025OduwacoinÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáISO 13407ISO 3103ÌbàdànÈṣùISO 19439Elisabeti KejìJakartaLÈlòISO 15926 WIPISO 4217ISO 10383ISO 9897George MinotISO 27799MultibusDavid WoodardKòréà GúúsùMediaWikiOperating SystemAaliyahAmòfinISO 14644-6ISO 3977Ipa ajakaye arun COVID-19 lori ona ati asa adayebaISO 13406-2KarachiEdward Adelbert DoisyCôte d'Ivoire15107 ToepperweinKọ́nsónántì èdè YorùbáPetra CetkovskáISO 14651ISO/IEEE 11073ASEANIṣẹ́ Àgbẹ̀Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèISO 16750ISO/IEC 18000Quett Masire.suJoseph GoebbelsJoel McHale22 February135 filmAbrahamuTorxSam SmithFidio ereAlthea GibsonISO 3166-2.gwBrusselsISO 4157Karl MarxISO 3307ÀrokòISO 9362Wiki CommonsẸ̀sìnISO/IEC 7812JBIG🡆 More