Ìmòye

Ìmòye (Philosophia; Philosophy) ni igbeka awon isoro gbogbo ati pipilese lori ohun bi iwalaye, imo, iyi, ironu, emi ati ede.

O yato si awon ona idojuko ibere pipilese (bi Iseawo, itan-abiso tabi awon iseona) nipa ona oniyewo, ati ni gbogbo ona sistemu ati igbokan le re lori iyan alalaye. "Philosophy" (filosofi) wa lati ede Griki φιλοσοφία (philosophia), to tumo si "ife oye".

Àwọn ẹ̀ka ìmòye

Ìwọ̀nyí ni àwọn ẹ̀ka ti won je gbigbeka ju lo:

  • Oro-adanida ni igbeka eda wiwa ati aye. Awon eka re ni oro-igbeaye and oro-iwalaaye.
  • oro-ijinle nje mo eda ati ise imo, atipe boya imo se e se. Ninu re ni ti ri isoro iseiyemeji ati ibasepo larin ooto, igbagbo, ati idalare.
  • Iwawiwu, tabi "imoye oniwayiyeni", bere bawo ni eni gbodo se huwa tabi boya iru ibere bahun gan ni idahun. Awon eka re ni oro-iwawiwu, ìṣe iwawiwu, ati imulo iwaiwu. oro iwawiwu nda lori eda ero oniwa, afiwe orisi awon sistemu oniwuwa, boya awon ooto oniwawiwu kedere wa, ati bi iru ooto bayi se le je mimo. Bakanna iwawiwu je jijose mo arowa ijeiwatoyeni. Awon iwe dialogi Plato ti bere mupo iwadi fun itumo idara.
  • Imoye olselu ni igbeka ijoba ati ibasepo awon enikookan ati awon agbajo mo orileijoba. O mupo awon ibere nipa idajo, ohun didara, ofin, ini ati awon eto ati ojuse omoilu.
  • Oro-ewa da lo ri ewa, ona, igbadun, awon iyi sensory-emotional, ihansi, ati nipa iwu ati italara.
  • Ogbon je igbeka awon iru ijiyan afesemule. Lati opin orun 19th, awon onimo mathimatiki bi Frege teju si fifi mathimatiki se ogbon, loni oro nipa ogbon pin si meji: ogbon mathimatiki (formal symbolic logic; ogbon ami-idamo) ati eyi ti a mo loni bi ogbon onimoye.
  • Ìmòye ẹ̀mí nda le eda emi ati ibasepo re mo ara, o se pataki nitori ijiyan larin ìṣeẹ̀mí meji ati iseohunaye. Apa imoye yi na tun ni ibasepo mo sayensi oloye.
  • Imoye ede n se awari eda, ibere ati ilo ede.
  • Imoye esin ni apa imoye to un bere awon ibere nipa esin.




Itokasi

Tags:

Greek language

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

GíríìsìÈdè Rọ́síàÀwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 1956Èdè YorùbáAzerbaijanAyéÌhìnrere MárkùHọ̀ndúràsOṣù KẹrinÒdòdóHAllahỌ̀rúndún 21kNapoleon 3kOmikíkanAgbègbè àkókòOrin hip hopÒmìniraSARS-CoV-2Hassan RouhaniMartin LutherAnnona squamosaeÌbonẸ̀yà ara ìfọ̀Paul OmuÈdè ṢáínàOṣù Kínní 21Ẹ̀sìn IslamLusakaBobrisky8 September18 NovemberÀwọn Ìdíje Òlímpíkì24 DecemberÀjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 2020ṢìkágòGúúsù ÁfríkàGámbíàErékùṣù ÀjíndeWúrà27 DecemberAudio Video InterleaveÒkun Árktìkì67085 OppenheimerWeb browserOrílẹ̀-èdè7 AugustTitun Mẹ́ksíkòItan Ijapa ati AjaOpen AustrálíàFrançois AragoLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀12 JuneMáltà9 FebruaryFrancisco FrancoOwóEdward Victor Appleton6 MarchÌjídìde FránsìAl Sharpton13 AprilÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáOdunlade AdekolaÌjà fẹ́tọ̀ọ́ Obìnrin🡆 More